Àwọn Ọba Keji 3:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí wọ́n dé ibùdó-ogun náà, àwọn ọmọ ogun Israẹli kọlù wọ́n, títí tí wọ́n fi sá pada; wọ́n sì ń pa wọ́n ní ìpakúpa bí wọ́n ti ń lé wọn lọ.

Àwọn Ọba Keji 3

Àwọn Ọba Keji 3:19-25