Àwọn Ọba Keji 25:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn ọmọ ogun Kalidea lépa Sedekaya, wọ́n bá a ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jẹriko, gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sì túká kúrò lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:1-14