Àwọn Ọba Keji 25:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹsan-an oṣù kẹrin, ìyàn náà mú láàrin ìlú tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn eniyan kò fi rí oúnjẹ jẹ mọ́.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:2-6