Àwọn Ọba Keji 25:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoiakini bọ́ aṣọ ẹ̀wọ̀n kúrò lọ́rùn, ó sì ń bá ọba jẹun lórí tabili ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:24-30