Àwọn Ọba Keji 25:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni gbogbo wọn, àtọmọdé, àtàgbà, ati àwọn olórí ogun bá gbéra, wọ́n kó lọ sí Ijipti, nítorí ẹ̀rù àwọn ará Kalidea bà wọ́n.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:16-27