Àwọn Ọba Keji 25:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kó àwọn ìkòkò, àwọn ọ̀kọ̀, àwọn ọ̀pá tí wọ́n fi ń pa iná lẹ́nu àtùpà, àwọn àwo turari ati àwọn ohun èlò bàbà tí wọ́n máa ń lò fún ìsìn ninu ilé OLUWA.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:13-16