Àwọn Ọba Keji 24:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mọkanlelogun ni Sedekaya nígbà tí ó wà lórí oyè, ó sì jọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkanla. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hamutali, ọmọ Jeremaya ará Libina.

Àwọn Ọba Keji 24

Àwọn Ọba Keji 24:16-20