Àwọn Ọba Keji 24:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà ni àwọn ọmọ ogun Nebukadinesari, ọba Babiloni, lọ gbógun ti Jerusalẹmu, wọ́n sì dó tì í.

Àwọn Ọba Keji 24

Àwọn Ọba Keji 24:1-11