Àwọn Ọba Keji 23:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò gba àwọn alufaa náà láàyè láti ṣiṣẹ́ ninu ilé OLUWA, ṣugbọn wọ́n lè jẹ ninu àkàrà tí wọn kò fi ìwúkàrà ṣe, tí ó jẹ́ ti àwọn alufaa ẹlẹgbẹ́ wọn.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:4-10