Àwọn Ọba Keji 23:22 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí pé wọn kò ti ṣe Àjọ̀dún Àjọ Ìrékọjá mọ́ láti àkókò àwọn onídàájọ́ ati ti àwọn ọba Israẹli ati Juda.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:16-27