Àwọn Ọba Keji 23:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn lọ sí ilé OLUWA pẹlu àwọn alufaa ati àwọn wolii ati gbogbo àwọn eniyan, àtọmọdé àtàgbà wọn. Ọba bá ka ìwé majẹmu tí wọ́n rí ninu ilé OLUWA sí etígbọ̀ọ́ wọn.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:1-3