Àwọn Ọba Keji 23:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Josaya ọba fọ́ àwọn òpó òkúta túútúú, ó gé àwọn ère oriṣa Aṣera, ó sì kó egungun eniyan sí ibi tí wọ́n ti hú wọn jáde.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:10-19