Àwọn Ọba Keji 22:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣafani jíṣẹ́ ọba fún Hilikaya; Hilikaya olórí alufaa, sì sọ fún un pé òun ti rí ìwé òfin ninu ilé OLUWA. Ó fún Ṣafani ní ìwé náà, ó sì kà á.

Àwọn Ọba Keji 22

Àwọn Ọba Keji 22:6-9