Àwọn Ọba Keji 22:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe ohun tí ó dára lójú OLUWA, ó tẹ̀ sí ọ̀nà Dafidi, baba ńlá rẹ̀, kò sì ṣe nǹkankan tí ó lòdì sí àpẹẹrẹ tí Dafidi fi lélẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 22

Àwọn Ọba Keji 22:1-9