Àwọn Ọba Keji 22:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé wọ́n ti kọ̀ mí sílẹ̀, wọ́n ń sun turari sí àwọn oriṣa láti mú mi bínú nítorí iṣẹ́ ọwọ́ wọn. Nítorí náà, inú mi yóo ru sí ibí yìí, kò sì ní rọlẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 22

Àwọn Ọba Keji 22:11-20