Àwọn Ọba Keji 21:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ati pé bí àwọn ọmọ Israẹli bá júbà àṣẹ mi, tí wọ́n pa òfin mi, tí Mose, iranṣẹ mi, fún wọn mọ́, n kò ní jẹ́ kí á lé wọn kúrò lórí ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá wọn.”

Àwọn Ọba Keji 21

Àwọn Ọba Keji 21:7-18