Àwọn Ọba Keji 21:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan Juda pa àwọn tí wọ́n dìtẹ̀ mọ́ Amoni ọba, wọ́n sì fi Josaya ọmọ rẹ̀ jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 21

Àwọn Ọba Keji 21:19-26