Àwọn Ọba Keji 21:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Manase kú, wọ́n sì sin ín sinu ọgba Usa tí ó wà ní ààfin. Amoni ọmọ rẹ̀, sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 21

Àwọn Ọba Keji 21:16-26