Àwọn Ọba Keji 20:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya ọba bèèrè pé, “Kí ni yóo jẹ́ àmì pé OLUWA yóo wò mí sàn, ati pé n óo lọ sí ilé OLUWA ní ọjọ́ kẹta?”

Àwọn Ọba Keji 20

Àwọn Ọba Keji 20:3-15