Àwọn Ọba Keji 20:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya sọ fún Aisaya pé, “Ọ̀rọ̀ OLUWA tí o sọ dára.” Nítorí ó wí ninu ara rẹ̀ pé, alaafia ati ìfọ̀kànbalẹ̀ yóo sá wà ní àkókò tòun.

Àwọn Ọba Keji 20

Àwọn Ọba Keji 20:12-21