Àwọn Ọba Keji 20:17 BIBELI MIMỌ (BM)

‘Àkókò kan ń bọ̀ tí wọn yóo kó gbogbo ohun tí ó wà ninu ààfin rẹ lọ sí Babiloni, gbogbo ohun tí àwọn baba ńlá rẹ ti kó jọ látẹ̀yìnwá títí di òní ni wọn óo kó lọ, wọn kò ní fi nǹkankan sílẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 20

Àwọn Ọba Keji 20:11-19