Àwọn Ọba Keji 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Aadọta ninu àwọn ọmọ àwọn wolii náà sì dúró ní òkèèrè, wọ́n ń wò wọ́n. Elija ati Eliṣa sì dúró létí odò Jọdani.

Àwọn Ọba Keji 2

Àwọn Ọba Keji 2:3-9