Àwọn Ọba Keji 2:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà ó mú aṣọ àwọ̀lékè Elija tí ó bọ́ sílẹ̀, ó sì pada lọ dúró ní etí odò Jọdani.

Àwọn Ọba Keji 2

Àwọn Ọba Keji 2:5-16