Àwọn Ọba Keji 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti ń lọ tí wọ́n sì ń sọ̀rọ̀, lójijì kẹ̀kẹ́-ogun iná ati ẹṣin iná gba ààrin wọn kọjá, Elija sì bá ààjà gòkè lọ sí ọ̀run.

Àwọn Ọba Keji 2

Àwọn Ọba Keji 2:7-12