Àwọn Ọba Keji 19:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kò sí ohun tí n kò mọ̀ nípa rẹ,mo mọ àtijókòó rẹ, àtijáde rẹati àtiwọlé rẹ, ati bí o ti ń ta kò mí.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:23-36