Àwọn Ọba Keji 19:25 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣé o kò mọ̀ péó pẹ́ tí mo ti pinnu àwọn nǹkan tí ó ń ṣẹlẹ̀ wọnyi ni?Èmi ni mo fún ọ ní agbáratí o fi sọ àwọn ìlú olódi di òkítì àlàpà.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:19-34