Àwọn Ọba Keji 19:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí OLUWA sọ nípa Senakeribu ni pé,‘Sioni yóo fi ojú tẹmbẹlu rẹ,yóo sì fi ọ́ ṣe ẹlẹ́yà;Jerusalẹmu yóo fi ọ́ rẹ́rìn-ín.’

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:15-26