Àwọn Ọba Keji 19:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya ọba gba ìwé náà lọ́wọ́ àwọn iranṣẹ, ó kà á. Lẹ́yìn náà, ó lọ sí ilé OLUWA, ó tẹ́ ìwé náà sílẹ̀ níwájú OLUWA.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:13-16