Àwọn Ọba Keji 18:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì ṣí wúrà tí ó wà lára ìlẹ̀kùn ilé OLUWA ati wúrà tí òun tìkararẹ̀ fi bo àwọn òpó ìlẹ̀kùn, ó kó wọn ranṣẹ sí Senakeribu.

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:12-19