Àwọn Ọba Keji 18:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹrinla tí Hesekaya jọba ní Juda, ni Senakeribu, ọba Asiria, gbógun ti àwọn ìlú olódi Juda, ó sì ṣẹgun wọn.

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:5-23