Àwọn Ọba Keji 18:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba Asiria kó àwọn ọmọ Israẹli ní ìgbèkùn lọ sí Asiria, ó sì kó wọn sí ìlú Hala ati Habori tí ó wà ní agbègbè odò Gosani ati sí àwọn ìlú àwọn ará Media.

Àwọn Ọba Keji 18

Àwọn Ọba Keji 18:9-16