Àwọn Ọba Keji 17:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí OLUWA ti fi ìyapa sí ààrin Israẹli ati ìdílé Dafidi, Israẹli fi Jeroboamu ọmọ Nebati jọba. Jeroboamu mú kí wọ́n kọ OLUWA sílẹ̀, ó sì mú kí wọ́n dẹ́ṣẹ̀ ńlá.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:11-22