Àwọn Ọba Keji 17:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA bínú sí àwọn ọmọ Israẹli, ó sì run wọ́n kúrò níwájú rẹ̀, ṣugbọn ó fi Juda nìkan sílẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:17-24