Àwọn Ọba Keji 17:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n rú gbogbo òfin OLUWA Ọlọrun wọn; wọ́n yá ère ẹgbọ̀rọ̀ akọ mààlúù meji, wọ́n ń sìn wọ́n. Wọ́n gbẹ́ ère oriṣa Aṣera, wọ́n sì ń bọ àwọn ohun tí ó wà lójú ọ̀run ati oriṣa Baali.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:6-22