Àwọn Ọba Keji 17:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn wọn kò gbọ́, wọ́n jẹ́ ọlọ́kàn líle bí àwọn baba ńlá wọn, tí wọn kò gba OLUWA Ọlọrun wọn gbọ́.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:7-24