Àwọn Ọba Keji 16:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ogún ọdún ni Ahasi nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè fún ọdún mẹrindinlogun. Kò tẹ̀lé àpẹẹrẹ rere Dafidi baba ńlá rẹ̀, ṣugbọn ó ṣẹ̀ sí OLUWA Ọlọrun rẹ̀,

Àwọn Ọba Keji 16

Àwọn Ọba Keji 16:1-3