Àwọn Ọba Keji 16:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé Ahasi fẹ́ tẹ́ ọba Asiria lọ́rùn, ó gbé pátákó tí wọ́n tẹ́ fún ìtẹ́ ọba kúrò, ó sì sọ ibẹ̀ dí ẹnu ọ̀nà tí ọba ń gbà wọ ilé OLUWA.

Àwọn Ọba Keji 16

Àwọn Ọba Keji 16:11-20