Àwọn Ọba Keji 16:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ki Ahasi tó dé, Uraya bá mọ irú pẹpẹ ìrúbọ náà, gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ tí Ahasi rán sí i láti Damasku.

Àwọn Ọba Keji 16

Àwọn Ọba Keji 16:9-15