Àwọn Ọba Keji 15:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kú, wọ́n sì sin ín sinu ibojì àwọn ọba ní ìlú Dafidi, Jotamu, ọmọ rẹ̀, sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:1-11