Àwọn Ọba Keji 15:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Jotamu kú, wọ́n sin ín sinu ibojì àwọn ọba ní ìlú Dafidi; Ahasi ọmọ rẹ̀, sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:34-38