Àwọn Ọba Keji 15:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kò pa àwọn pẹpẹ ìrúbọ run, àwọn eniyan ṣì ń rú ẹbọ, wọ́n sì ń sun turari níbẹ̀. Òun ni ó kọ́ ẹnu ọ̀nà apá ìhà àríwá ilé OLUWA.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:30-38