Àwọn Ọba Keji 15:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni nígbà tí ó jọba, ó sì jọba fún ọdún mẹrindinlogun ní Jerusalẹmu. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jeruṣa, ọmọ Sadoku.

Àwọn Ọba Keji 15

Àwọn Ọba Keji 15:25-38