Àwọn Ọba Keji 14:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe nǹkan burúkú lójú OLUWA; ó tẹ̀lé ìwà ẹ̀ṣẹ̀ Jeroboamu, ọmọ Nebati, tí ó mú Israẹli dẹ́ṣẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 14

Àwọn Ọba Keji 14:14-27