Àwọn Ọba Keji 14:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dìtẹ̀ mọ́ Amasaya Ọba ní Jerusalẹmu, ó sì sá lọ sí Lakiṣi. Ṣugbọn wọ́n rán eniyan lọ bá a níbẹ̀, wọ́n sì pa á.

Àwọn Ọba Keji 14

Àwọn Ọba Keji 14:18-20