Àwọn Ọba Keji 14:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọwọ́ Jehoaṣi tẹ Amasaya, lẹ́yìn náà, ó lọ sí Jerusalẹmu, ó wó odi Jerusalẹmu lulẹ̀ láti Ẹnubodè Efuraimu títí dé Ẹnubodè Igun, gbogbo rẹ̀ jẹ́ irinwo igbọnwọ (400 mita).

Àwọn Ọba Keji 14

Àwọn Ọba Keji 14:12-23