Àwọn Ọba Keji 14:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Amasaya kọ̀ kò gbọ́, nítorí náà, Jehoaṣi ọba Israẹli kó ogun lọ pàdé Amasaya ọba Juda ní Beti Ṣemeṣi tí ó wà ní Juda.

Àwọn Ọba Keji 14

Àwọn Ọba Keji 14:10-15