Àwọn Ọba Keji 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe nǹkan burúkú lójú OLUWA, ó tẹ̀lé ìwà ẹ̀ṣẹ̀ Jeroboamu, ọmọ Nebati, tí ó mú Israẹli ṣẹ̀, kò sì fi ẹ̀ṣẹ̀ náà sílẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 13

Àwọn Ọba Keji 13:1-6