Àwọn Ọba Keji 13:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo nǹkan yòókù tí Jehoaṣi ṣe ati ìwà akọni rẹ̀ ninu ogun tí ó bá Amasaya, ọba Juda, jà ni a kọ sinu Ìwé Ìtàn Àwọn Ọba Israẹli.

Àwọn Ọba Keji 13

Àwọn Ọba Keji 13:4-13