Àwọn Ọba Keji 12:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Joaṣi pàṣẹ fún àwọn alufaa pé kí wọ́n máa kó àwọn owó ohun mímọ́ tí wọ́n mú wá sí ilé OLUWA pamọ́: ati gbogbo owó tí àwọn eniyan san fún ẹbọ ìgbà gbogbo ati èyí tí wọ́n mú wá gẹ́gẹ́ bí ọrẹ àtinúwá.

Àwọn Ọba Keji 12

Àwọn Ọba Keji 12:1-12