Àwọn Ọba Keji 12:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olórí ogun Joaṣi ọba dìtẹ̀ mọ́ ọn, wọ́n sì pa á ní ilẹ̀ Milo ní ọ̀nà tí ó lọ sí Sila.

Àwọn Ọba Keji 12

Àwọn Ọba Keji 12:14-21